Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ọjọ́ náà, ni èmi yóò se àwọn baálẹ̀ Júdà bí ààrò iná kan láàrin igi, àti bi ẹfúùfù iná láàrin ìtí; wọn yóò sì jẹ gbogbo àwọn ènìyàn run yíká lápá ọ̀tún àti lápá òsì: a ó sì tún máa gbé inú Jérúsálẹ́mù ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin Sekaráyà 12

Wo Sekaráyà 12:6 ni o tọ