Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì wí fún mi pé, “Ṣọ ọ sí àpótí ìsúra!” Iye dáradára náà, tí wọn yọ owó mi sí. Mo sì mu ọgbọ̀n owo fàdákà náà, mo sì sọ wọ́n sí àpótí ìsúra ní ilé Olúwa.

Ka pipe ipin Sekaráyà 11

Wo Sekaráyà 11:13 ni o tọ