Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanáyà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbègbè náà yóò sì jẹ́ ti ìyókù àwọn ilé Júdà,níbẹ̀ ni wọn yóò sì ti rí ìjẹ fún ẹran,Ní ilé Áṣíkélónì ni wọn yóòdùbúlẹ̀ ni àṣálẹ́. Olúwa Ọlọ́run wọn yóò bojútó wọn,yóò sì yí ìgbékùn wọn padà.

Ka pipe ipin Sefanáyà 2

Wo Sefanáyà 2:7 ni o tọ