Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanáyà 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ni fún ẹ̀yin tí ń gbé etí òkun,ẹ̀yin ènìyàn ara Kérétì;Ọ̀rọ̀ Olúwa dojúkọ ọ́, ìwọ Kénánì,ilẹ̀ àwọn ara Fílísítíà.Èmi yóò pa yín run,ẹnìkan kò sì ní ṣẹ́kù nínú yín;

Ka pipe ipin Sefanáyà 2

Wo Sefanáyà 2:5 ni o tọ