Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanáyà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi yóò mú ènìyàn àti ẹrankokúrò; èmi yóò mú àwọn ẹyẹ ojúọ̀run kúrò àti ẹja inú òkun, àtiohun ìdìgbòlù pẹ̀lú àwọnènìyàn búburú; èmi yóò ké ènìyàn kúrò lórí ilẹ̀ ayé,”ni Olúwa wí

Ka pipe ipin Sefanáyà 1

Wo Sefanáyà 1:3 ni o tọ