Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanáyà 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ọrọ̀ wọn yóò di ìkógún,àti ilé wọn yóò sì run.Àwọn yóò sì kọ́ ilé pẹ̀lú, ṣùgbọ́nwọn kì yóò gbé nínú ilé náà,wọn yóò gbin ọgbà àjàrà,ṣùgbọ́n wọn kì yóò mu ọtíWáìnì láti inú rẹ̀.

Ka pipe ipin Sefanáyà 1

Wo Sefanáyà 1:13 ni o tọ