Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 97:9-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Nítorí pé ìwọ, Olúwa, ní ó ga ju gbogbo ayé lọìwọ ni ó ga ju gbogbo òrìsà lọ.

10. Jẹ kí gbogbo àwọn tí ó fẹ́ Olúwa, kórira ibi, ó pa ọkan àwọn ènìyàn mímọ́ Rẹ̀ mọ́ó gbà wọ́n ní ọwọ́ àwọn ènìyàn búburú.

11. Ìmọ́lẹ̀ tàn sórí àwọn olódodoàti ayọ̀ nínú àlàyé ọkàn

12. Ẹ yọ̀ nínú Olúwa, ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ olódodo,kí ẹ sì yin orúkọ Rẹ̀ mímọ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 97