Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 93:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa ń jọba, ọlá ńlá ní ó wọ̀ ní aṣọ;ọlá ńlá ni Olúwa wọ̀ ní aṣọàti ìhàmọ́ra Rẹ̀ pẹ̀lú agbára.Ó fi ìdí ayé múlẹ̀;kò sì le è yí.

Ka pipe ipin Sáàmù 93

Wo Sáàmù 93:1 ni o tọ