Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 92:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ohun rere ni láti máa fi ọpẹ́ fún Olúwaàti láti máa kọrin sí orúkọ Rẹ̀, Ọ̀gá ògo,

2. Láti kéde ìfẹ́ Rẹ̀ ní òwúrọ̀àti òtítọ́ Rẹ̀ ní alẹ́

Ka pipe ipin Sáàmù 92