Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 90:14-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. Tẹ́wa lọ́rùn ní òwúrọ̀ nínú ìṣeun ìfẹ́ Rẹ,kí àwa kí o le kọrin fún ayọ̀kí inú wa sì dùn ní gbogbo ọjọ́.

15. Mú inú wa dùn bí ọjọ́ tí ìwọ ti pọ́n wa lójú,fún ọjọ́ pípọ̀ tí àwa ti rí wàhálà.

16. Jẹ́ kí a fi iṣẹ́ Rẹ̀ hàn àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ Rẹ̀,ògo Rẹ̀ sì àwọn ọmọ wọn.

17. Jẹ́ kí ẹwa Olúwa Ọlọ́run wa wà lára wa;fí ìdí iṣẹ ọwọ́ wa múlẹ̀ lára wabẹ́ẹ̀ ní kí ó sì ìdí iṣẹ́ ọwọ́ wa múlẹ̀.

Ka pipe ipin Sáàmù 90