Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 89:50-52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

50. Rántí, Olúwa, bí àti ń gan àwọn ìránṣẹ́ Rẹ;bí èmi ti gbà ní àyà mi láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn,

51. Ẹ̀gàn tí àwọn ọ̀tá Rẹ gàn, Olúwa,tí wọn gan ipaṣẹ̀ Ẹni àmì òróró Rẹ.

52. Olùbùkún ní Olúwa títí láé.Àmín àti Àmín.

Ka pipe ipin Sáàmù 89