Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 89:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èmi kọrin títóbi ìfẹ́ Olúwa títí láé;pẹ̀lú ẹnu mi ní èmi yóò jẹ́ kí a mọ̀ òtítọ́ Rẹ láti ìran dé ìran.

2. Èmi ó wí pé, ìfẹ́ Rẹ dúró títí láé,pe ìwọ gbe òtítọ́ Rẹ kalẹ̀ ní ọ̀run fúnrarẹ.

3. Ìwọ wí pé, “Èmi ti dá májẹ̀mu pẹ̀lú àwọn àyànfẹ́ mimo ti búra fún Dáfídì ìránṣẹ́ mi.

4. Èmi ó fi ìdí irú ọmọ Rẹ múlẹ̀ títí láéèmí ó sì máa gbe ìtẹ́ Rẹ ró láti ìran dé ìran”.

Ka pipe ipin Sáàmù 89