Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 88:13-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Ṣùgbọ́n mo kígbe sí ọ fún ìrànlọ́wọ́, Olúwa;ní òwúrọ̀ ní àdúrà mí wá sọ́dọ̀ Rẹ.

14. Olúwa, èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ mítí ìwọ fi ojú Rẹ pamọ́ fún mi?

15. Láti ìgbà èwe mi, ìṣẹ́ ń ṣẹ́ mi,èmi múra àti kú;nígbà ti ẹ̀ru Rẹ ba ń bà mí,èmi di gbére-gbère

16. Ìbínú Rẹ ti kọjá lára mi;ìbẹ̀rù Rẹ ti ge mi kúrò

17. Ní gbogbo ọjọ́ ní wọn yí mi ká bí ìkún omi;wọ́n mù mí pátápátá.

Ka pipe ipin Sáàmù 88