Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 87:6-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Olúwa yóò kọ nínú àkọsílẹ̀ àwọn ènìyàn Rẹ̀:“Eléyìí ni a bí ní Síónì.”

7. Àti àwọn olorin àti àwọn ti ń luohun èlò orin yóò wí pé,“Gbogbo orísun mi ń bẹ nínú Rẹ.”

Ka pipe ipin Sáàmù 87