Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 85:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìwọ fi ojú rere han fún ilé Rẹ, Olúwa;ìwọ mú ohun ìní Jákọ́bù bọ̀ sí pò.

2. Ìwọ dárí àìṣedédé àwọn ènìyàn Rẹ̀ jìnìwọ sì bó ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀. Sela

3. Ìwọ fi àwọn ìbínú Rẹ sápá kanìwọ sì yípadà kúrò nínú ìbínú gbígbóná Rẹ.

Ka pipe ipin Sáàmù 85