Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 84:9-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Wo àsà wa, Ọlọ́run;fi ojú àánú wò àwọn ẹni àmì òroro Rẹ.

10. Dídára ní ọjọ́ kan ní ààfin Rẹju ẹgbẹ̀rún ọjọ́ lọ;èmi o kúkú máa ṣe aṣọ́nà nínú ilé Ọlọ́run miju láti gbé ní àgọ́ àwọn ènìyàn búburú.

11. Nítorí Olúwa Ọlọ́run jẹ́ òòrun àti àṣà; Olúwa fúnni ní ojúrere àti ọlá;kò sí ohun rere kan tí yóò fàsẹ́yìn dádúrófún àwọn tí o rin ní aílábùkù.

12. Olúwa àwọn ọmọ-ogun,ìbùkún ni fún ọkùnrin náà tí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ.

Ka pipe ipin Sáàmù 84