Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 84:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòotọ́ ologóṣẹ ri ilé,ẹyẹ alápáǹdẹ̀dẹ̀ tẹ́ ìtẹ́ fún ara r,níbi tí yóò máa pá ọmọ Rẹ̀ mọ́ sí:ibùgbé ní tòsí pẹpẹ Rẹ, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, ọba mí àti Ọlọ́run mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 84

Wo Sáàmù 84:3 ni o tọ