Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 84:11-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Nítorí Olúwa Ọlọ́run jẹ́ òòrun àti àṣà; Olúwa fúnni ní ojúrere àti ọlá;kò sí ohun rere kan tí yóò fàsẹ́yìn dádúrófún àwọn tí o rin ní aílábùkù.

12. Olúwa àwọn ọmọ-ogun,ìbùkún ni fún ọkùnrin náà tí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ.

Ka pipe ipin Sáàmù 84