Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 81:13-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. “Bí àwọn ènìyàn mi yóò bá gbọ́ tèmibí Ísírẹ́lì yóò bá tẹ̀lé ọ̀nà mi,

14. Ní kánkán ni èmi yóò ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá wọnkí ń sì yí ọwọ́ mi padà sí ọ̀tá wọn!

15. Àwọn tí ó kórìíra Olúwa yóò tẹríba níwájú Rẹ̀.Ìjìyà wọn yóò sì pẹ́ títí láé

16. Ṣùgbọ́n a ó fi ọkà tí ó dára bọ́ ọ́ yínèmi ó tẹ́ ẹ yín lọ́rùn pẹ̀lú oyin inú àpáta.”

Ka pipe ipin Sáàmù 81