Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 8:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Ìwọ ṣeé ní onírẹ̀lẹ̀ díẹ̀ ju ẹ̀dá ọ̀run lọìwọ sì dée ní adé ògo àti ọlá.

6. Ìwọ mu-un jọba lórí gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ Rẹ;ìwọ si fi ohun gbogbo sí abẹ́ ẹsẹ̀ Rẹ̀:

7. gbogbo ọ̀wọ́ ẹran àti agbo ẹran,àti ẹranko ìgbẹ́,

Ka pipe ipin Sáàmù 8