Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 8:4-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. kí ni ènìyàn tí ìwọ ń rò nípa Rẹ̀,ọmọ ènìyàn tí ìwọ ń ṣe ìtọ́jú Rẹ̀?

5. Ìwọ ṣeé ní onírẹ̀lẹ̀ díẹ̀ ju ẹ̀dá ọ̀run lọìwọ sì dée ní adé ògo àti ọlá.

6. Ìwọ mu-un jọba lórí gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ Rẹ;ìwọ si fi ohun gbogbo sí abẹ́ ẹsẹ̀ Rẹ̀:

7. gbogbo ọ̀wọ́ ẹran àti agbo ẹran,àti ẹranko ìgbẹ́,

8. ẹyẹ ojú ọrun,àti ẹja inú òkun,àti ohun tí ń wẹ nínú ipa òkun.

9. Olúwa, Olúwa wa,Orúkọ Rẹ̀ ti ní ìyìn tó ní gbogbo ayé!

Ka pipe ipin Sáàmù 8