Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 77:11-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Èmi ó rántí iṣẹ́ Olúwa:bẹ́ẹ̀ ni, èmi ó rántí iṣẹ́ ìyanu Rẹ̀ ọjọ́ pípẹ́.

12. Èmi ṣàṣárò lórí iṣẹ́ Rẹ gbogbopẹ̀lú, ènìyàn sì máa sọ̀rọ̀ gbogbo iṣẹ́ agbára Rẹ.

13. Ọlọ́run, Ọ̀nà Rẹ jẹ́ mímọ́.Ọlọ́run wo ní ó sì tóbi bí Ọlọ́run wa?

14. Ìwọ ni Ọlọ́run tó ń ṣe ìyanu;ìwọ fi agbára Rẹ hàn nínú àwọn ènìyàn.

Ka pipe ipin Sáàmù 77