Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 75:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọwọ́ Olúwa ni ago kan wà,ọtí wáìnì náà sì pọ́n,ó kún fún àdàlú, ó fún ọtí àdàlú tí a pòpọ̀ mọ́ òórùn dídùntí ó tú jáde, àti búburú ayé gbogbomú u sílẹ̀ pátapáta.

Ka pipe ipin Sáàmù 75

Wo Sáàmù 75:8 ni o tọ