Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 75:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. A fi ìyìn fún ọ, Ọlọ́run,a yìn ọ́, nítorí orúkọ Rẹ̀ súnmọ́ tòsí;àwọn ènìyàn ń sọ ti ìyanu Rẹ.

2. Ìwọ wí pé, “Mo yan àkókò ìyàsọ́tọ̀;Èmi ni ẹni tí ń ṣe ìdájọ́ òdodo.

Ka pipe ipin Sáàmù 75