Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 74:7-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Wọ́n sun ibi mímọ́ Rẹ̀ lulẹ̀wọ́n ba ibùgbé orúkọ Rẹ̀ jẹ́

8. Wọ́n wí ní ọkàn wọn. “Àwa ó run wọ́n pátapáta!”Wọ́n sun gbogbo ibi ìjọ́sìn Ọlọ́run ní ilẹ̀ náà.

9. A kò fún wa ní àmì iṣẹ́ ìyanu kankan;kò sí wòlíì kankanẹnìkan kan wa kò mọ ìgbà tí eléyìí yóò dà.

Ka pipe ipin Sáàmù 74