Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 74:20-23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Bojúwo májẹ̀mu Rẹ,nítorí ibi òkùnkùn ayé kún fún ibùgbé ìkà.

21. Má ṣe jẹ́ kí àwọn aninilára padà sẹ́yìn nínú ìtìjújẹ́ kí àwọn aláìní àti talákà yin orúkọ Rẹ.

22. Dìde, Ọlọ́run, gba ẹjọ́ ara Rẹ̀ rò;rántí bí àwọn aṣiwèrè ti ń kẹ́gàn Rẹ ní gbogbo ọjọ́.

23. Má ṣe gbàgbé ohun àwọn ọ̀tá Rẹ,bíbú àwọn ọ̀tá Rẹ, tí ó ń pọ̀ síi nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Sáàmù 74