Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 74:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọlọ́run, èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ wá sílẹ̀ títí láé?Èéṣe tí ìbínú Rẹ̀ fi dìde sí àwọn àgùntàn pápá Rẹ?

2. Rántí àwọn ènìyàn tí ìwọ ti rà nígbà àtijọ́,ẹ̀yà ilẹ̀ ìní Rẹ, tí ìwọ ti ràpadàÒkè Síónì, níbi tí ìwọ ń gbé.

3. Yí ẹṣẹ̀ Rẹ̀ padà sí ìparun ayérayé wọn,gbogbo ìparun yìí tí ọ̀ta ti mú wá sí ibi mímọ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 74