Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 72:9-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Àwọn tí ó wà ní ihà yóò tẹríba fún unàwọn ọ̀ta Rẹ̀ yóò máa lá erùpẹ̀ ilẹ̀.

10. Àwọn ọba Táṣíṣì àti tí erékùṣùwọn yóò mú ọrẹ wá fún un;àwọn ọba Ṣéba àti Síbàwọn o mú ẹ̀bùn wá fún-un.

11. Gbogbo ọba yóò tẹríba fún-unàti gbogbo orílẹ̀ èdè yóò sìn ín.

12. Nítorí yóò gba àwọn aláìnínígbà tí ó bá ń ké,tálákà àti ẹní tí kò ni olùrànlọ́wọ́.

13. Yóò káànú àwọn aláìlera àti aláìníyóò pa aláìní mọ́ kúrò nínú ikú.

Ka pipe ipin Sáàmù 72