Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 71:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nínú Rẹ̀, Olúwa, ní mo ní ààbò;Má ṣe jẹ́ kí ojú kí ó tì mí.

2. Gbà mí kí ó sì tú mi sílẹ̀ nínú òdodo Rẹ;kọ etí Rẹ sími kí o sì gbà mí.

3. Jẹ́ àpáta ààbò mi,nibi tí èmi lè máa lọpa àṣẹ láti gbà mí,nítorí ìwọ ni àpáta àti asà mi.

4. Gbà mí, Ọlọ́run mi, lọ́wọ́ àwọn olùṣe búburú,ní ọwọ́ aláìsòdodo àti ìkà ọkùnrin.

Ka pipe ipin Sáàmù 71