Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 69:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe dójú tì àwọn tí ó ní ìrètí nínú Rẹnítorí mi, Olúwa, Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun;Má ṣe jẹ́ kí àwọn tó ń wá ọ dààmú nítorí mi,Ọlọ́run Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Sáàmù 69

Wo Sáàmù 69:6 ni o tọ