Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 66:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọ́run, gbogbo ayé!

2. Ẹ kọrin ọ̀lá orúkọ Rẹ̀;Ẹ fún un ní ìyìn, ògo,

3. Ẹ wí fún Ọlọ́run “pé,ìwọ ti ní ẹ̀rù tó nínú iṣẹ́ Rẹ̀!Nípa ọ̀pọ̀ agbára Rẹ ni àwọn ọ̀táRẹ yóò fi sìn ọ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 66