Ní tòótọ́, asán ní àwọn ọmọ ènìyàn, èkési ni àwọn olóyè, wọn gòkè nínú ìwọ̀nbákan náà ni wọn fẹ́rẹ̀ jù asán lọlápapọ̀ wọn jẹ èémí.