Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 60:10-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Kí ha ń ṣe ìwọ, Ọlọ́run, tí ó ti kọ̀ wá sílẹ̀tí o kò sì bá ogun wa jáde mọ́?

11. Fún wa ní ìrànlọ́wọ́ lórí àwọn ọ̀tá,nítorí asán ní ìrànlọ́wọ́ ènìyàn.

12. Nípa Ọlọ́run ni a ó ní ìṣẹ́gun,yóò sì tẹ̀ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Sáàmù 60