Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 54:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Jẹ́ kí ibi padà sẹ́yìn sí àwọn tí ń sọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ sí mi;pa wọ́n run nínú òtítọ́ Rẹ.

6. Èmí yóò rú ẹbọ àtinúwá sí ọèmi yóò yin orúkọ Rẹ, Olúwa,nítorí tí ó dára.

7. Nítorí tí ó yọ mí kúrò nínú ibi gbogboojú mi ti wo ìborí lórí ọ̀ta mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 54