Nígbà náà ni inú Rẹ yóò dùn sí ẹbọ òdodo,pẹ̀lú ọrẹ-ẹbọ sísun àti ọ̀tọ̀tọ̀ ọrẹ ẹbọ sísun,nígbà náà ni wọn yóò fi akọ màlúù rúbọ lórí pẹpẹ Rẹ̀.