Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 51:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Sàánú fún mi, Ọlọ́run, gẹ́gẹ́ bíìdúró sinsin ìfẹ́ Rẹ̀,gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ àánú Rẹ̀kí o sì pa gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi rẹ́.

2. Wẹ gbogbo àìṣedédé mi nù kúròkí o sì wẹ̀ mi mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ mi!

Ka pipe ipin Sáàmù 51