Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 43:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Ran ìmọ́lẹ̀ àti òtítọ́ Rẹ jáde,jẹ́ kí wọn ó máa dààbò bò mí;jẹ́ kí wọn mú mi wá sí òkè mímọ́ Rẹ,sí ibi tí ìwọ ń gbé.

4. Nígbà náà ní èmi o lọ sí ibi pẹpẹ Ọlọ́run,sí Ọlọ́run ayọ̀ mí àti ìdùnnú mi,èmi yóò yin ọ pẹ̀lú dùùrù,ìwọ Ọlọ́run, Ọlọ́run mi.

5. Èéṣe tí o fi ń rẹ̀wẹ̀sì, ìwọ ọkàn mí?Èéṣe tí ó fi ń ru sókè nínú mi?Fi ìrètí Rẹ sínú Ọlọ́run,nítorí èmi yóò máa yìn ín, Òun niOlùgbàlà mi àti Ọlọ́run mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 43