Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 41:11-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Èmi mọ̀ pé inú Rẹ̀ dùn sí mi,nítorí ọ̀tá mi kò borí mi.

12. Bí ó ṣe tèmi niìwọ dì mí mú nínú ìwà òtítọ́ miìwọ sì gbé mi kalẹ̀ níwájú Rẹ títí láé.

13. Olùbùkún ni Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lìláé àti láéláé.Àmín àti Àmín.

Ka pipe ipin Sáàmù 41