Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 4:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló ń béèrè pé, “Ta ni yóò ṣe rere fún wá?” Olúwa, Jẹ́ kí ojú Rẹ mọ́lẹ̀ sí wa lára,

7. Ìwọ ti fi ayọ̀ púpọ̀ kún ọkàn miju ìgbà tí hóró irúgbìn àti wáìnì tuntun wọ́n pọ̀ fún mi lọ.

8. Èmi yóò dùbúlẹ̀, èmi ó sì sùn ní àlàáfíà,nítorí ìwọ nìkan, Olúwa, ni omú mi gbé láìléwu.

Ka pipe ipin Sáàmù 4