Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 39:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ti ṣe ayé mibí ìbú àtẹ́lẹwọ́,ọjọ́ orí mi sì dàbí asánní iwájú Rẹ:Dájúdájú olúkúlùkù ènìyàn nínúìjókòó rere Rẹ̀ jásí asán pátapáta. Sela

Ka pipe ipin Sáàmù 39

Wo Sáàmù 39:5 ni o tọ