Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 39:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Mo wí pé,èmi yóò ṣọ́ ọ̀nà mikí èmi kí ó má fi ahọ́n mi ṣẹ̀èmi yóò fi ìjánu kó ara mi ní ẹnuníwọ̀n ìgbà tí ènìyàn búburúbá ń bẹ ní iwájú mi.

2. Mo fi ìdákẹ́ ya odi;mo tilẹ̀ pa ẹnu mi mọ́kúrò nínú ọ̀rọ̀ rere;ìbànújẹ́ mi sì pọ̀ síi.

Ka pipe ipin Sáàmù 39