Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 37:32-35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

32. Ènìyàn búburú ń ṣọ́ olódodo,Ó sì ń wá ọ̀nà láti pa á.

33. Olúwa kì yóò fi lé e lọ́wọ́kì yóò sì dá a lẹ́bi,nígbà tí a bá ń ṣe ìdájọ́ Rẹ̀.

34. Dúró de Olúwa,kí o sì má a pa ọ̀nà Rẹ̀ mọ́,yóò sì gbé ọ lékèláti jogún ilẹ̀ náà:Nígbà tí a bágé àwọn ènìyàn búburú kúrò ìwọ yóò ri.

35. Èmí ti rí ènìyàn búburútí n hu ìwà ìkà,ó sì fi ara Rẹ̀ gbilẹ̀ bíigi tútù ńlá.

Ka pipe ipin Sáàmù 37