Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 37:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Má ṣe ìkanra nítorí àwọnolùṣe búburú,kí ìwọ má sì ṣe ṣe ìlàra nítorí àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀;

2. nítorí pé wọn yóò gbẹbí koríko,wọn yóò sì Rẹ̀ dànùbí ewéko tútù

3. Gbẹ́kẹ̀lé Olúwa,kí o sì máa ṣe rere;torí pé ìwọ yóò gbé ilẹ̀ náà,kí o sì gbádùn ààbò Rẹ̀

Ka pipe ipin Sáàmù 37