Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 35:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí ìparun kí ó wá síorí wọn lójijì.Àwọ̀n Rẹ̀ tí ó dẹ pamọ́,kí ó mú àwọn tìkálára wọn;kí wọn ṣubú sínú kòtòsí ìparun ara Rẹ̀.

Ka pipe ipin Sáàmù 35

Wo Sáàmù 35:8 ni o tọ