Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 31:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmí ti sọ nínú ìdágìrì mi,“A gé mi kúrò ní ojú Rẹ!”Ṣíbẹ̀ ìwọ́ ti gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi fún àánúnígbà tí mo ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 31

Wo Sáàmù 31:22 ni o tọ