Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 31:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi di ẹni ẹ̀gàn láàrin àwọn ọ̀tá mi gbogbo,pẹ̀lú pẹ̀lú láàrin àwọn aládùúgbò mi,mo sì di ẹ̀rù fún àwọn ojúlùmọ̀ mi;àwọn tí ó rí mi ní òde ń yẹra fún mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 31

Wo Sáàmù 31:11 ni o tọ