Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 31:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nínú Rẹ̀, Olúwa ni mo ti rí ààbò;Má ṣe jẹ́ kí ojú kí ó tì mí;gbà mí nínú òdodo Rẹ.

2. Tẹ́ etí Rẹ sí mi,gbà mí kíákíá;jẹ́ àpáta ààbò mi,jẹ́ odi alágbára láti gbà mí.

3. Ìwọ pàápàá ni àpáta àti ààbò mi,nítorì orúkọ Rẹ máa ṣe ìtọ́ mi tọ́ mi kí o sì ṣe amọ̀nà mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 31