Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 30:9-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. “Èrè kí ni ó wà nínú ikú ìparun mi,nínú lílọ sí ihò mi?Eruku yóò a yìn ọ́ bí?Ǹjẹ́ yóò sọ nípa òdodo Rẹ?

10. Gbọ́, Olúwa, kí o sì ṣàánú fún mi;ìwọ Olúwa, jẹ́ olùrànlọ́wọ́ mi.”

11. Ìwọ ti yí ìkáànú mi di ijó fún mi;ìwọ sì ti bọ́ aṣọ ọ̀fọ̀ mi, o sì fi aṣọ ayọ̀ wọ̀ mí,

12. nítorí ìdí èyí ni kí ọkàn mi máa yìn ọ́, kí ó má sì ṣe dákẹ́.Ìwọ Olúwa Ọlọ́run mi, èmi yóò máa fi ọpẹ́ fún ọ títí láé.

Ka pipe ipin Sáàmù 30