Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 29:5-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Ohùn Olúwa fọ́ igi kédárì; Olúwa náà ló fọ́ igi kédárì Lébánónì.

6. Ó mú Lébánónì fo bí i ọmọ màlúù,àti Síríónì bí ọmọ àgbáǹréré.

7. Ohùn Olúwa ń yabí ọwọ́ iná mọ̀nà

8. Ohùn Olúwa ń mi ihà. Olúwa mi ihà Kádéṣì.

Ka pipe ipin Sáàmù 29