Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 27:12-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Má ṣe fi mí lé ìfẹ́ àwọn ọ̀ta mi lọ́wọ́,nítorí àwọn ẹlẹ́rìí èké ti dìde sí mi,wọ́n sì mí ìmí ìkà.

13. Èmi ní ìgbàgbọ́ péèmi yóò rí ìre Olúwaní ilẹ̀ alààyè.

14. Dúró de Olúwa;kí ó jẹ alágbára, kí o sì mú ọkàn leàní dúró de Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 27